File size: 18,871 Bytes
324441a
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42
43
44
45
46
47
48
49
50
51
52
53
54
55
56
57
58
59
60
61
62
63
64
65
66
67
68
69
70
71
72
73
74
75
76
77
78
79
80
81
82
83
84
85
86
87
88
89
90
91
92
93
94
95
96
97
98
99
100
101
102
yo_review	sentiment
Ìyanilẹ́nu!. . Eré ṣíṣe tó dára, gbígbé eré jáde náà rewà, ìtọ́sọ́nà tó wuyì.. .  . . Eré  yìí jẹ́ ìgbésí ayé. Mó jókò ó sí orí sónsó ìjòkó mi fún wákàti méje wíwo eré  náà	positive
Ó jẹ́ eré tí ó níse pẹ̀lú ǹkan tó o Kári ayé.	positive
Ere tó dára púpọ̀ fún àwọn ọmọdé láti wò. . .  . . Ere tó dára púpọ̀ fún àwọn ọmọdé láti wò ni Mirror Boy. Ere tó dùn tí a ṣe dáadáa tó sì kọ àwọn ọmọdé lẹ́kọ̀ọ́ ni ere yìí. Orin inú ere náà rẹwà ó sì dùn láti gbọ́.	positive
Àti rí̀ Richard Mofe-Damijo (RMD) tó kó ipa Ejiro, ọmọ ìta tó ti fèyìntì fún ọ̀gá ọ̀daràn yàtọ̀ sí ipa tó máa ń kó tẹ́lẹ̀ bíi bàbá olówó. Ó sì ṣe dáadáa.	positive
Ní ọjọ́ kini oṣù kẹjọ, ayẹyẹ Ijade mú ká rí ọpọlọpọ àwọn ènìyàn ju ẹyẹ àwọn ẹni ta n'reti lọ.. .  . . Eré orí ìtàgé yìí jẹ eré tó sọ nípa bí àwọn ènìyàn tó ngbé ní àwọn ìlú tó lajú diẹ ṣe ngbiyanju láti lè bọ́ lọwọ ìgbé ayé wọn tí tẹlẹ àti bí gbé ayé wọn tẹlẹ ní ṣe pẹlu ọjọ ọla wọn.. .  . . Níbi ayẹyẹ Ijade ile ìwé, baba dipo padà. Gbogbo àwọn ará mọlẹbi nìí oníkálukú bí òun o ṣe dá sí ìpàdé bọ rẹ. Sugbon àwọn tó tí rí tẹlẹ gbọdọ tí borí ìgbà tó fí kọ́kọ́ kúrò àti ìdí tí ọ fi tún padà wá ikẹdun wà tí sún kúrò.. .  . . Àwọn òṣèré tó ya eré orí ìtàgé náà gbìyànjú àti pé ìtàn inú eré natú sí ìta bikòṣe nipa ará rẹ. Òun tó nwụni lórí ní	positive
O jọnilójú. .  . . Ìpìlẹ tó dára tí a dá pọ pẹlú ìsíyèméjì ati ìgbàgbọ asán, o ṣe sọ tẹlẹ dè òpin pẹlu ìpìlẹ̀ lílò tí o dáa. Mo nifẹ iṣẹ Kunle Afoláyan, ẹni tí o má n kópa nínú iṣẹ tí o bá n kọ, darí tí o sí má n gbé jáde. O le ṣẹ̀ ọpọlọpọ iṣẹ́,èyí tí o jọnilójú	positive
Dokita Lanre jẹ ìyípadà tó dùn moní.. . Inu mi dun wipe mo wà lára àwọn ti o kọkọ wá nínú reluwe eré yii. Ìyípadà ti o dun mo ni ni o jẹ. Ìtàn na ni ìpìlẹ ti o dára tí wọn sì gbé jade dáadáa nipasẹ ìkópa awọn òṣèré ti o kún oju oṣuwọn.. . Eré tó yẹ fún wíwò.	positive
Gẹ́gẹ́ bí Adenike, Gurira jẹ́ ohun àgbàyanu: Bákan náà ni ojú rẹ̀ ń dán yálà ó ń ṣe àfihàn ìdààmú tàbí ayọ̀, ó sì mú àwọn ọ̀nà tí obìnrin yìí, tí ó jẹ́ arúgbó tí ń ṣe ojúṣe, tún fẹ́ darapọ̀ mọ́ ayé òde òní.	positive
Èyí tó dára jùlọ	positive
Eré tó dára.. .  . . Eré tó tayọ, nínú àìní àfojúsùnn ọjọ́ iwájú ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà pẹ̀lú gbogbo àìlera rẹ̀, ìrètí nínú ìsòtítọ́ àti ìsọ̀kan akín yorísí ìdàrúdàpọ̀. Ìkópa dídára òṣèré obìnrin ní àfikún sí afojusun lati mu ànfàní àsìkò ìpayà àti àìlágbára lọ. Eré tó dára pẹlú akoko ẹdọfu.	positive
Eré tó dára fún àmì ẹ̀yẹ. .  . . Eré tó dára fun àmì ẹ̀yẹ ati àwọn òsèré  inúu rẹ̀ ṣe dáadáa àti  eré tó se bẹbẹ.	positive
Ìtàn ńlá nìyí.. . Sinimá tó yáyì gidi ni. Ó sọ nípa ìbàjẹ́ àwùjọ wá. Ó bani lọ́kàn jẹ́ ṣùgbọ́n òótọ́ ni.	positive
Ó mú kí kíkọ́ síi nípa ìtàn Nàìjíríà wùmi. Èyíkéyìí eré tí ó bá mú mi láti kọ́ ẹ̀kọ́ síi á gba òṣùwọ̀n ìràwọ mérin nínú ìwé mìi.	positive
Sinimá gidi tí ó ń kó àyà ẹni sókè ni. . Ní àkọ́kọ́, mò ń wò ó bóyá yóò dára àbí pé ìdàkejì rẹ̀ nítorí n kò fi bẹ́ẹ̀ mọ̀ nípa àwọn sinimá Nàìjíríà tẹ́lẹ̀. Àmọ́ ní òpin fíìmù yìí (eléyìí tí wọ́n rí ṣe dáadáa), mo wá gbà pé mo ṣẹ̀ṣẹ̀ fojú kojú pẹ̀lú fánrán ohùn àti àwòrán tí kò ní ẹgbẹ́ ni.. . Mo le è fi ọwọ́ rẹ̀ sọ àyà pé kí àwọn ènìyàn wò ó.	positive
Eré tó dára pẹlú idapọ asa ni ona tó dára. Ẹkọ pọ lati kọ latara obìnrin akínkanjú to gbìyànjú láti já ipo re ninu Aye tó awọn ọkunrin joba le lori. Eré tó dára gidigidi.	positive
O dara, e pa àtúnyẹwò òdì tí. .  . . Ní tòótọ,o ya ni lẹ́nu , mi kò gbàgbọ́ wípé Nàìjíríà ni wón ti ṣe, iṣẹ́ - lọ́pọ̀ rẹ jẹ́ pàtàkì, àwọn òṣeré rẹẹ ṣé mú yangàn. Gbogbo wọn ṣa ipá wọn dáa dáa,o sí dùn.	positive
Ìwádìí tímọ́tímọ́ tí ó gbé àwọn ìdojúkọ abiyamọ jáde.	positive
Nǹkan tuntun . .  . . Pẹ̀lúpẹ̀lú u bí a kò ṣe gba ti ere yìí, mo lérò pé gbogbo wàhálà Namaste yẹ ní wíwò bí kò tilẹ̀ ju iṣẹ̀jú kan lọ fún ṣíṣe nǹkan tuntun tó yàtọ̀.	positive
Fíìmù to dara. . Mo feran itan na. Mo feran sise Eré ati wipe itan na ba awon nkan ti o n sele ni awujo wa.	positive
“Farming” ń fa ìrora ní wíwò, ṣùgbọ́n Idris jẹ́ ìràwọ tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń gbórísókè. Beckinsale náà kàmìmì gẹ́gẹ́ bí ìyá àwọn Tilbury.	positive
Eré àgbéléwò onígbàdún uǹ	positive
Fún ere náà ní ẹ̀yẹ díẹ̀.. . Ó dá bíi pé Fíìmù  náà ń wuni, ó sì ní àwọn ìwà ipá burúkú díẹ̀, ṣùgbọ́n mo ríi gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó jẹ́ pàtàkì láti sọ ìtàn náà.	positive
Fíìmù apanilẹ́rìn-ín. .  . . Ere yìí kúnn ẹ̀rín. Mo kàn ń rẹ́rìn ni láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin.	positive
Èyí dára.. . Hmmm... Ere àgbéléwò gidi nìyí, kò jù bẹ́ẹ̀ lọ.	positive
Won se fún iṣẹju merin din ni adọrin, ọmọ ifijiṣẹ (The Delivery Boy) je ojúlówó ìtumò wípé dídára lori ọpọ. Fíìmù yìí je ìkan lára àwọn fíìmù gidi ti o ti jade ni  ọdọ Nollywood. Awọn to ṣe ní òye láti pa ìtàn ti o dára tí o sí pelu ìmọ - ẹrọ tó dára.. .  . .  . .  . . A gbádùn rẹ nígbà tí a woni èní, bẹ sí ní akojọpọ eniyan ti a ko wo. Gbogbo wa la kuro ni iyara láì ni ìbànújẹ. O sí dá wa lójú pé bẹ mi o ṣe rí fún eyin naa. Ọmọ ifijiṣẹ náà(The Delivery Boy)ko pẹ, ṣugbọn a lè sọ fúnn pẹlu ìgboyà wipe,tí e bá ní fíìmù tí o jẹ kẹ sanwo fún láti wò tí e sì lè tí lẹyìn,ọmọ ifijiṣẹ náà(The Delivery Boy) ni o yẹ kó jẹ. O ní ìgboyà o sí tún tẹ síwájú.	positive
Eré àgbéléwò dára!	positive
Ó yàtọ̀ gedegbe sí àtẹ̀yìnwá.. . Mo ti wo ọ̀pọ̀lọpọ̀ Fíìmù  tí wọ́n ṣe ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Jíjẹ́ ògidì wọn máa ń yàtọ̀ nípa ipa ìtàn, àgbékalẹ̀ cinema náà, eré ṣíṣe, àti bí ohùn ṣe dára sí. Fíìmù  yìí tayọ ju gbogbo àwọn yòókù ní gbogbo ọ̀nà.	positive
Wiwa ti ọjọ ori dramedy ti o padanu ọna rẹ ni awọnna opopona ti Afirika ode oni.	positive
Eré Nigeria Prince tayọ nínú ètò rẹ̀, èyí losi jẹ kí o jẹ àfikún sí àwọn eré ti o nííṣe pẹ̀lú ọ̀ràn	positive
Kẹ̀rẹ̀ kẹ̀rẹ̀ ó ń rẹwà bọ̀. Eré àgbéléwò yìí dá lórí ọ̀rẹ́ àti ìgbà èwe méjì tó ja ìjà oríṣiríṣi ìdíwọ́ láti wà papọ̀	positive
Ìdarí eré àgbéléwò àkọ́kọ́ tó níyì. .  . . Mo ṣàwárí rẹ̀ nínú eré àgbéléwò “Tubi”, mo gbádùn rẹ̀. Ó ní ibi tó fì sí ṣùgbọ́n eré àgbéléwò náà dára.. . Eré àgbéléwò tó dára ni.	positive
Irọ́ mà ń jọ òtítọ́. Ṣé lòótọ́?	positive
Lákòótán, ó dùn bi ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù Nollywood, kò ṣòro láti mọ̀; àwọn alátakò àti àwọn tí ò kin ṣe alátakò kò ṣòro dá mọ.	positive
Eré àgbéléwò yìí nílò ìyìn tó ju eléyìí lọ torípé ó jẹ́ eré ṣìṣe tí akójọpọ̀ àwọn  ìsẹ̀lẹ̀ rẹ̀ kún ojú òsùwọ̀n. Mi ò tíì rí eré àgbéléwò nípa àjàkálẹ̀ àrùn bayii ri, eléyìí jẹ́ titun.	positive
Mo nifé eré àgbéléwò  yìí , àmọ́ mi ò tilẹ̀ le sọpé bóyá eni bayi lókú tàbí eni bayìí ni ko kòkú. Eré èrùjèjè ni. Bí ó ti lẹ̀ jẹ́pẹ́ ọmọ odún méje ni mí, eru o si ba mi. Mo máa fún ní méfà lórí òṣùnwọ̀n.	positive
Eré tó mórí wú , tó sì mórí yá , àti pé o fi hàn gedengbe pe Ìtàn ìrírí ayé ni.	positive
Ó fínjú. Eré ṣíṣe àti ìtàn eré nà dára, ṣùgbọ́n igbéjáde eré na kù díẹ̀ ká tó. Parí parí eré nà dára.	positive
Eré àgbéléwò alágbára to ń fọwọ́ tọ́ni lọ́kàn.	positive
Ko sọ́rọ̀ púpò lórí rẹ̀. Eré gidi  tó dá lórí  òṣèlú ìlú-ọba	positive
Àwọn ìpele kọ̀ọ̀kan nínú eré àgbéléwò yìí tọ́ni lọ́ọ́kàn.  Ìwọ náà wòó.	positive
Ipá ohùn tó tayọ. .  . . Eré àgbéléwò yìí dára. Àwọn òṣèré na jáfáfá. Ìparí eré na rújú ṣùgbọ́n ipa ohùn je èyí tó dára jù nínú oríṣiríṣi tí mo ti gbó nínú àwọn eré àgbéléwò ti Nàìjíríà dẹ̀ní.	positive
Eré àgbéléwò to dára sùgbón o fun àwọn omo odún méjìdílógún sókè.. . Eré àgbéléwò to dára fáwọn ọmọ odún méjìdílógún sókè.  Mo gbádùn eré na jálè.	positive
Eré àgbéléwò aládùn tó sì ṣíni lójú. . Eré àgbéléwò yii fi òrò ifiranse pàtàki si àwọn oun to ń lo nínú ìlú  . Gbogbo ipele nínú eré  lo dùn wò.	positive
Ìgbésè ìgbóyà tó wúni lórí. .  . . Dájúdájú mo gbádùn eré àgbéléwò yìí… pàápàá ju lọ èmi ti ń kin wo eré àgbéléwò ti Nàìjíríà ( tàbí ka pè ní Nollywood?)	positive
Ìyàlẹ́nu lónà àrà	positive
Ìgbésè nla nínú ilé-isé ìgbé sinimá jáde. .  . . Àwọn òsèré ti wọ́n lò dara , wọ́n sì kopà ìpín wọ́n dáradára .  Wón gbìnyànju . O je àrídájú to dára fun àwọn eré àgbéléwò ti Nàìjíríà.	positive
Eré sinimá na mọ́n. Ó kún fún àwọn gbajúgbajà òṣèré, eré náà jágeree, o si tun tóka si  àwọn ìsèlè to ń dàmú orílè-èdè  Nàìjíríà	positive
Ó yé àwọn adúláwọ̀ tó wà ní òkè òkun dáradára. Ó sọ nípa ìrírí ì mi gẹ́gẹ́ bíi adúláwọ̀ tí kò gbé nílẹ adúláwọ̀ tí ó sì ń gbìyànjú láti wá ibùgbé mìíràn.Fíìmù tó dára.	positive
Gbogbo bí ìwà ìbàjẹ́ tí burú tó ni sinimá yìí fi hàn.	positive
Ere yìí jé ìtàn tòótọ́ tí ó sì jẹ ìṣe ọpọlọ	positive
òsì paraku . . . Ọ̀nà ìkọtàn yí burú jù . Mi ò lè mú ra mi láti wò ó dé ìparí .	negative
Ní ọ̀pọ̀ ìgbà, wọn kìí tẹpá mọ kíkọ ìtàn ère sinimá. Sinimá yìí kàn rí bákan ṣá.	negative
bóbá sejẹ́, tí obá mọ̀ ẹnìkankan rí óye kí ó jẹ ìyà, rà tíkẹ́ẹ̀tì	negative
Ọ̀kan tí ó burú,. . pẹ̀lú ariwo yìí,  mo lérò pé eréoníṣe tó tayọ nì í ṣùgbọ́n eléèyí jẹ́ ọ̀kan nínú  èré tó burú jáì tí mo ti rí nígbà  díẹ̀	negative
Mo tilẹ̀ ń wa ilẹ̀ láàkọ́kọ́ Ere náà ni àkókò ṣùgbọ́n Oni ìṣòro ìfàyèsí ,o nilo í ṣàtúnṣe , àti pé otun gun	negative
Ṣé ẹlòmíràn gbà pẹ̀lú mi wípé ohun tí wọn fi síwájú kàn  dàbí àgbélébùú láàrín Àǹtónì Mákì àti Dáníẹ́lì Kàlúyà ni?	negative
Fíìmù òmùgọ̀	negative
Thecall'  jẹ́ oun tí kò dàgbà	negative
Ohun gbogbo dàbí ẹnipé kò ní ibi-afẹ́dé, kékeré, bí ẹnipé ìtàn náà (èyítí ó jẹ́ ni àwọn àkókò tí kò ní ìdáríjì) kò ṣe ìṣeré bí ó ṣe ṣe jáde nìkan tí ó yára kọja.	negative
"Eré yìí kò dára rárá fún ẹnikẹ́ni títí kan àwọn ọmọdé. Eré tó ń run ènìyàn ninu ni eré ""Another Father's Day"". Eré tó lè ru ìbínú sókè nínú ènìyàn ni eré yìí. Ò̩nà eré sís̩e yii kò gbé iṣé̩ o̩po̩lo̩ jáde rárá. Eré tó lè mú kí ènìyàn má nífẹ̀é̩ sí Nollywood ni eré yìí jé̩. Ìfowó àtàkókò àti agbára ṣòfò ni. Àtúbọ̀tán ère o̩ló̩mo̩kúùyà nìyí. A rọ̩ àwọ̩n olólùfẹ́ ère àgbéléwò láti má fi àkókò wọn ṣòfò lórí irú ère yìí."	negative
Mọ́kàndílọ́gbọ̀n nínú ọgọrun	negative
pàdánù ànfàní	negative
Wákàtí méjì ṣòfò. . Kìí ṣe oun ti mo retí, eré nàà kúnn ẹ̀fẹ̀ tó nní nínú.	negative
Ìtàn yẹn kò ṣe ohun kankan lára tèmi jàre.. . Nígbà tí ó yá, mo lè sọ ohun tí yóò tẹ̀lé ohun tí wọ́n ń ṣe lọ́wọ́. Wọ́n tilẹ̀ tún wà ń ṣe àtúnṣe àwọn ohun tí wón ṣe tẹ́lẹ̀ nígbà tí yóò fi di ìgbẹ̀yìn eré yìí.	negative
Ìf'àkókò ṣòfò. . Eré náà kò yéni tó, kò m'ọ́pọlọ dáni, ò kúnn ọmọ Nàìjíríà tón se àsìlo ọ̀rọ̀ Jàmáíkà.	negative
Kìí ṣe ti lílo oun apanilérìn, iṣẹ́ àti ìjà ṣùgbón pẹ̀lú bí kò ṣe dáa tó a máa ṣeni ní kàyéfì.	negative
Eré onífẹ̀ẹ́ apani lẹ́rìnn níbi tí ilé ìdáná, ilé ìtura àti orílẹ̀-èdè tí à ń rí níbí kò ti jọ ara wọn.	negative
Èmi yóò fẹ́ láti jẹ́ ... apániláyà. . Àwàdà tí a  wò ní ìgbà pípẹ́	negative
Kò kọjá. Ó jẹ́ ìdánilárayá. Kò yanilẹ́nu.	negative
Mi ò fọwọ́ rẹ̀ sọ̀yà. Ìtàn tó dára gidigidi ni ṣugbọn àwọn ẹ̀bùn tí ò sọ kò kún tó.	negative
Mo fẹ́ràn fíìmù yìí. . Ṣùgbọ́n mi ò kàn le sé náàni. Gbígbé lọ́ra ṣùgbọ́n tún jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀. Ó mà burú gan ò.	negative
Ní gbogbo ọ̀nà ni sinimá yìí kò fi dáa rárá. Ó s’eni láàánú pé ó dín díẹ̀ nínu wákàti méjì àkókò ayé mi ni mo fi ṣòfò lórí eré yìí.	negative
Midnight Crew' jẹ́ eré kan tí kò dùn tí ènìyàn ni láti yẹra fún ní sinimá.	negative
Agbara miiran ti o dara ti bajẹ nipasẹ kikọ buburu.	negative
Pàpá Ajasco wá sí sinimá ní ìyàlẹ́nu ìyàlẹ́nu àti àwàdà aṣiwèrè aṣiwèrè yìí.	negative
Mo fẹ́ láti fẹ́ràn fíìmù yìí gaan. Mo ní ìfẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣèré àti dídára ìṣelọ́pọ̀.Ó dára, ṣùgbọ́n bótilẹ̀jẹ́pé ó jẹ́ wákàtí kan nìkan etí ọgbọ̀n ìṣẹ́jú mẹ́rin, ó dàbí pé ó fá lórí láíláí. Mo ní láti dúró àti bẹ̀rẹ̀ fíìmù yìí. Mo ti párí níkẹhìn lẹ́hìn osù díẹ̀.	negative
Ó dùn mí pé mo fi àkókò ṣòfò lórí eré yìí	negative
Ìbànújẹ́ pé ohùn orin púpọ̀ ló wà jákèjádò fíìmù náà àti pé ó ní ipa tí ṣíṣe fíìmù náà ní ìmọ́lára ẹni ọgbọ̀n ọdún.	negative
Máse gbọ́kànle díwọ̀n Ìgbéohùn kan jáde	negative
ìdọ̀tí pípẹ́	negative
Sinimá yìí burú débi wípé, kò sí àsopọ̀ láàrin ìbẹ̀rẹ̀ àti àwọn apá tó kù. Èyí kò bójúmu ṣùgbọ́n sinimá yìí lè dára jù báyìí lọ.	negative
Eré tí kò dára	negative
Ó dára títí di òpin . . Àṣìṣe ńlá!	negative
Mo nírètí jù báyìí lọ	negative
gélé tí wákàtí méjì kọjá, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ' ìpè láti òdò olórun'  kòdùn	negative
Èbùn ṣ'òfò. . Mo kúrò ní ilé ìwòran pẹ̀lú ìjákulẹ̀	negative
Èyí ni fíìmù tí ó bá jẹ jù tí mo ti wò rí	negative
Ọ̀rọ̀ tí kò l'agbára, àfihàn ìjà tí kò múná d'óko	negative
Fíìmù Fine wine 🍷 kò bá dùn ju báyìí lọ àmọ́ wọn kò rí ìtàn tí ó dára tó yẹn túmọ̀ dáadáa àti pé ohun tí ó tún báà jẹ́ ni bí wọ́n ṣe ń yọ́ bíi ìgbín.	negative
Mi ò le fọwọ́ rẹ̀ sọ̀yà	negative
Àsọdùn nípa eré tí kò dùn. . Àkójọpọ̀ òṣèré lè bí elòmíràn nínú	negative
bóse jpé Zebé Ejiro lóṣé tí  Chico Ejiro ló darí rẹ̀, àgbà òsèré méjì, ọkọ̀ alá lọ́sí èkó' kò délé láyọ̀. nígbà àtijọ́. ìfiwósòfò	negative
N kò le sọ fún ẹnikẹ́ni kí ó wo sinimá yìí. Wọ́n kàn lọ dá ohun tí àwọn kan ti ṣe tẹ́lẹ̀ ṣe ni.	negative
Sinimá tí kò dára rárá ni	negative
Titun. Ìgboyà.  àìmọ́gbọ́nwá. Àìtẹ́lọ́rún.	negative
"È̩hun olópòó kan ni, ó dára bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀.. . ""Lionheart"" jé̩ eré tó fa ọ̀pọ̀lọpọ̀ awuyewuye ni ilé-is̩é̩ Nollywood. Wó irú atile̩yin ilè̩ òkèèrè tó rí gbà ló̩wó̩ Netflix, inú èmi pàápàá dùn láti rí bí èrè yìí ṣe lọ. . . Láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹpẹ ni ère yìí tí sàfihàn pé tíwantiwa ni, kò sì pé̩ rárá tí a fi rí ìsò̩rò̩ǹgbèsì lédè Yorùbá. . .  . .  . .  . . Ṣùgbọ́n ère náà fihàn pe olópòó kan ni bí ó ṣe n tẹ̀ síwájú. . .  . .  . . È̩hun rẹ̀ kò ní ipa kankan, ketekete ni ènìyàn lè sọ nǹkan tó kàn nínú eré náà. Ìyàlẹ́nu ni èyí jẹ́. . .  . . Síbẹ̀síbẹ̀, mo sì gbóríyìn fún ìgbèjàde ère náà nítorí pé ó gbámús̩é àti pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀dá ìtàn ni wọ́n kó ipa wọn bí ó ṣe tọ́ àti bí ó ṣe yẹ̩ àyàfi Peter Okoye tó já wá kule. . .  . .  . . Fún tí ìdarí, àfi kí ènìyàn gbóríyìn fún ìgboyà Genevieve fun ìṣe takuntakun to ṣe. . .  . . Lákòótán, kò sí ìdánilójú pé wà á gbádùn ẹ̀fẹ̀ yìí bí ó ṣe lérò"	negative
Èmi gbà fún sinimá tí ó bá jẹ́ pé àwọn òșèré àti àwọn ibi tí wọ́n lò jẹ́ ti òkè òkun.	negative
Fíìmù ti o ni àwọn gbajúmò Òṣeré nínú sugbọn ṣíṣe rẹ kò dára rárá	negative
Kò fọwọ́sí. Dejavu jẹ àpẹẹrẹ eré Yorùbá	negative
Kò fọwọ́sí fun sinimá. Eré yìí ni wàhálà púpọ̀.	negative