id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_02895
Pogba: Ikọ̀ Real Madrid ń gbáradì láti kó £70m lé Paul Pogba lórí
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02896
Ọdun to n bọ niṣẹ yoo pari patapata lori atunṣe biriji afara ẹlẹẹkẹta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02897
Èèyàn bí ogún jóná kú lásìkò tí 'tanker' gbina ní Kogi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02898
Aṣiri tu, wọn ni Tinubu ti ni ki Ayedatiwa kọwe ifipo silẹ ti ko ni deeti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02899
Ẹṣọ oju-popo ti a ba ri ju 500 naira lọwọ re wọ gau
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02900
Adunni Ade: Lóòtọ́ọ́ ní àwọn adarí eré máa ń ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn òṣèré-bìnrin àmọ́ kò ṣẹlẹ̀ sí mi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02901
Adeoye Damilare disabled shoe maker: Bí ẹ̀sẹ̀ mi méjèjì ṣe dédé di jọwọlọ láàrin òru ọ̀gànjọ́ ní kékeré nìyí
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02902
Baba to ṣeku pa ọmọ ẹ lẹyin to ji i gbe ti ko sọwọ ọlọpaa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02903
Prophet TB Joshua: Ẹ̀gbọ́n tí TB Joshua fi sílẹ̀ lọ àti gbogbo ìlú kọ̀ láti jáde nílé torí ìsìnkú rẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02904
Wọn ni adigunjale ati ọmọ ẹgbẹ okunkun ni Jẹlili atawọn meji tọwọ ba l’Abẹokuta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02905
Xenophobia: Àwọn ọmọ South Africa ní àwọn kò rí ìṣẹ́ ṣe, kí àjèjì máa lọ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02906
Ó ṣeéṣe kí àwọn ẹlẹ́wọ̀n ó dìbò lọ́dún 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02907
Davido: Davido ní Wema Bank ń pe òun fún ìpàdé nítorí ẹ̀dáwó N1milion tó pè sí àṣùwọ̀n wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02908
Coronavirus lockdown: Ìyàtọ̀ láàrín ìgbélé ní Nàìjíríà àti ilẹ̀ òkèèrè
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02909
Sunday pa baba to fun un nilẹ ko fi maa dako l’Ọṣun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02910
Awọn SARS lo pa aburo mi-Mosun Filani
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02911
Proposed Police Strike: Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní àhesọ̀ ní pé àwọn òṣìṣẹ́ òun kan fẹ́ da iṣẹ́ sílẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02912
Aláàfin: Àìrí iṣẹ́ ṣe ọ̀dọ́ lágbègbè mi ń peléke, ó sì nílò àmójútó
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02913
Àwọn olùfẹ́hónúhàn dáná sun ọ̀pọ̀ ṣọ́ọ̀ṣì mẹ́ta àti mọ́ṣáláṣí ní Ethiopia
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02914
Baba Ijesha: Iyabo Ojo ní ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ti tú àṣírí báwọn oníwàkòtọ́ ṣe pọ̀ sí ní Nàìjíríà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02915
Ko daa bi Aarẹ ṣe fipa gbaṣẹ lọwọ awọn ọga ologun ilẹ yii – Sadeeq Shehu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02916
Cult attack in Osun Varsity: Wo ohun tó ṣẹlẹ̀ sí akẹ́kọ̀ọ́ fásìtì Osun táwọn ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn dáná sún
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02917
‘Awọn abinu-ẹni oloṣelu lo pa Bọla Ige’
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02918
Buhari: Baba 'Go slo' ní ìṣèjọba alágbádá ti ń falẹ̀ jù fún ipinnu òun gbogbo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02919
Oyo prison break: Ìbúgbàmù ọ̀hún kò mú ẹ̀mí ẹnikẹ́ni lọ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02920
Nitori ẹbun mọto tawọn ọmọ rẹ fun un lọjọọbi ẹ, Iya Fẹmi Adebayọ bu sẹkun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02921
Makẹta ti Tọpẹ bimọ fun b’ALAROYE sọrọ: N ko ni ẹjọ kankan pẹlu Ayọmikun, Tọpẹ ni ko jade waa sọrọ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02922
Tinubu ti tun tẹkọ leti lọ siluu oyinbo, eyi lohun to n lọọ ṣe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02923
Goriola Hassan: ‘Tattoo’ tó wà lára mi, kò dí ọba jíjẹ lọ́wọ́, ara oge ṣíṣe ni
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02924
Ogójì ọdún sẹyìn ní ọmọ wá kú ṣùgbọ́n arákùnrin yí gbè awọ àti orúkọ rẹ̀ wọ tó sì gbé ilẹ bàbá wà tà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02925
Priscila Tsegah CCTV: Ikú akẹ́kọ̀ọ́ ẹni ọdún 23, irú kí ló ṣẹlẹ̀ tí ọlópàá fí ba oku rẹ̀ nílé ìtura?
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02926
Awọn aṣofin Ogun dabaa pe ki ayajọ ọjọ Iṣẹṣe maa jẹ ọjọ isinmi lẹnu iṣẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02927
Dead body dumped beside church in Akure: Gbogbo èèyàn jí bá òkú náà nílẹ̀ ni, kẹ́nikẹ́ni má sọ ohun tí wọn kò mọ̀
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02928
A ti ṣe Naijiria daadaa ju ba a ṣe ba a lọdun 2015 lọ-Lai Muhammed
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02929
Wasiu ko ẹgbẹrun mẹwaa Naira fun agbanipa, o ni ko fi payawo oun toyun-toyun l’Ogijo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02930
Ẹnu iṣẹ ni nọọsi yii wa to ti ṣubu, lojiji, lo ba dagbere faye
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02931
Fight against corruption: Ọ̀rọ̀ Satguru Maharaj ji sí àwọn olóṣèlú Nàìjíríà lórí ìwà àjẹbánu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02932
Malaria Vaccine: Àjọ WHO gbé abẹ́rẹ́ àjẹsára àìsàn ibà jáde fún ilẹ̀ Afrika
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02933
Nigbẹyin, ẹgbẹ APC gba lati mu alaga wọn lati ilẹ Hausa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02934
A kò ní fààyè gba ọtí títà àti rírà lásìkò ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé – Ijọba Qatar
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02935
Seyi Makinde: Gbígbégilé ojú òpó Twitter yóò ba ọrọ̀ ajé Naijiria jẹ́ ní àgbáyé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02936
Kayeefi! Awọn agbebọn ji ọba ati olori rẹ gbe lọ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02937
FA Cup final Arsenal vs Chelsea: Lampard laná! Arsenal fa Chelsea ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ gba ife FA Cup
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02938
Awọn gomina PDP mẹrin ṣepade pẹlu Mimiko l’Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02939
Idi ti ko fi yẹ ki ilẹ Yoruba ṣe alaini – Oyetọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02940
Awọn eeyan Oriade ni ọlọpaa ko gbọdọ fi Jombo to n lẹdi apo pọ pẹlu awọn ajinigbe silẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02941
Christmas greetings: Kò sí ọdún tí ọjà ré tà tó ti Kérésì ọlọ́dọọdún- Alhaja Shakirat
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02942
Ẹgbẹ awọn Fulani pariwo : Wọn ti fẹẹ pa awọn eeyan wa tan ni Kwara o
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02943
Lẹyin to wọle ibo, Sanwo-Olu kede ẹkunwo fawọn oṣiṣẹ ọba l’Ekoo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02944
Tope Ajogbajesu: Mọ̀lẹ́bí kan ní orin ikú ọdún yìí fò mí ru ní Tope kọ láàrin ọ̀sẹ̀ tó kú
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02945
Emi ni mo kunju oṣuwọn ju lọ lati pese idari to maa tun nnkan ṣe daadaa ni Naijiria – Ọsinbajo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02946
₦2m ní Seyi Makinde ń fún Olopoeyan lọ́sẹ̀, wọ̀bìà ló mú kó kúrò nínú PDP - Auxillary
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02947
Awọn ọdọ pariwo ole le Pasuma lori nibi ti wọn ti n ṣewọde ta ko SARS l’Ekoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02948
Atiku ṣa fẹẹ fọwọ ara ẹ ṣera ẹ ṣaa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02949
Nitori ẹẹdẹgbẹta Naira, wọn l’ẹsọọ Amọtẹkun lu ọmọọdun mẹrinla pa l’Ondo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02950
#SagamuOnFire: Àwọn ẹbí Tiamiyu bèrè fún ìwádìí tòótó lórí ikú ọmọ wọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02951
Ọpẹ o! Iyawo Oluwoo, Olori Firdaus Akanbi, bimọ obinrin
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02952
Nitori Korona: Ijọ Ridiimu fagi le isin aisun-ọdun tuntun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02953
Sunday Igboho: Ẹ̀yin oríadé ẹ dìde, wàhálà ń bọ̀ nílẹ̀ Yorùbá, ọ̀dọ́ 10m fẹ́ jà fún Igboho
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02954
Ibo ku ọjọ kan, wọn ji oludije sipo igbakeji gomina gbe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02955
Ooni Ogunwusi: Ẹ sinmi àdíjàlẹ̀ ìròyìn, Adeleke kò ní òun yóò ra bàálù fún mi
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02956
Gomina AbdulRasaq atawọn ọba alaye ti pari ija Ibaruba ati Yoruba Kwara
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02957
Covid-19 Vaccine: Obìnrin kán sọ ìdí tí kò fi gba àjẹ́rẹ́ àjẹsára, tó sì pàdánù ìṣẹ́ rẹ̀
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02958
Awọn ọlọpaa ti mu Ahmed ati Ṣẹyẹ, wọn lawọn ni wọn pa Gafaru l’Abẹokuta
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02959
Hajj: Àjọ alálàájì ní owó Hajj ọdún yìí yóò tó N2.5m fún arìnrìnàjò kọ̀ọ̀kan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02960
Aṣọbode gba ẹru ofin to le ni ọgọrun-un kan miliọnu naira lọwọ awọn onifayawọ ni Kwara
0
0
0
1
0
1
yor
yor_train_track_a_02961
Adajọ sọ Maina to kowo awọn ọṣiṣẹ-fẹyinti jẹ sẹwọn ọdun mọkanlelọgọta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02962
Amọtẹkun bẹrẹ iṣẹ l’Ọyọọ, Makinde ko wọn jade bii ọmọ tuntun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02963
ASUU Strike: Àwọn ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ bèèrè ohun méjì lọ́wọ́ ìjọba, kí wọn tó fopin sí ìyanṣẹ́lódì
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02964
Davido and Dele Adeleke: Njẹ́ ọ̀rọ̀ ipò gómínà Osun ní 2022 kò fẹ́ ẹ̀ da ẹbí Adeleke rú báyìí?
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02965
Ademọla Adeleke balẹ sipinlẹ Ọṣun, o ni ki  Oyetọla maa palẹ ẹru rẹ mọ l’Abere
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02966
Kola Ologbondiyan: PDP ni yóò mú ọmọ Nàíjíríà kúrò lóko ìyà tí wọn wà ní 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02967
Ẹ woju ajinigbe to pa Nabeeha, ọkan ninu awọn ọmọbinrin mẹfa ti wọn ji
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02968
Akinyele killings: Ọwọ́ ọlọ́pàá ti tẹ Toheed Ganiyu tí wọ́n ló pa Mary Daramola ẹni ọdún 18 l'Akinyele ní ìlú Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02969
RCCG members kidnap: Ọlọ́pàá ní àwọn kò gbọ́ ohun kan nípa bó yá àwọn agbébọn jí ọmọ ìjọ RCCG mẹ́jọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02970
EndSARS kò tíì tán torí ìjọba kò tíì fi ọlọ́pàá àrúfin kankan jófin - Mr Macaroni
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02971
Awọn Fulani si fibọn fọ ẹnu iya yii, wọn tun ṣa a ladaa, nitori to ni ki wọn ma fi maaluu jẹ oko oun n’Ijẹbu-Oru
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02972
Nigeria debt profile: Níbi tí ìjọba àpapọ̀ ń bọ́rọ́ lọ àfàìmọ̀ káwọn tí Nàìjíríà jẹ ní gbèsè ó má fi ṣọfà, Atiku Abubakar ṣèkìlọ̀
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02973
Queen Elizabeth and Nigeria at 60: Obabinrin Elizabeth kí Nàìjíríà kú oríire òmìnira ọgọ́ta ọdún
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02974
Obinrin to ba ṣẹṣẹ bimo ni ipinlẹ Ọyọ, oṣu mẹfa ni yoo fi sinmi nile
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02975
Ijọba kede ọjọ Iṣẹgun ati Ọjọruu gẹgẹ bii ọlude ọdun Ileya
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02976
Ọwọ ọlọpaa tẹ awọn ajinigbe meji, wọn doola ọmọleewe ti wọn ji gbe
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02977
Lẹyin ọpọlọpọ awuyewuye, Ọmọdewu di alaga APC ipinlẹ Ọyọ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02978
Àánú ìjọba tó ń bọ̀ ń ṣe mí, torí nǹkan yóò nira – Sanusi
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02979
Wọn pa Fulani darandaran sinu oko, wọn tun ge ẹya ara rẹ lọ ni Kwara
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02980
Sunday Igboho's Yoruba Nation rally: Ẹ máa retí ìdájọ́ àwọn olùwọ́de Yoruba Nation tó wà láhàmọ́
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02981
Ọlọpaa o le sọ pe ka ma ṣewọde ayajọ EndSARS, a maa ṣe e -Oduala
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02982
Nitori afikun owo-epo bẹntiroolu ati ina ijọba, awọn eeyan bẹrẹ ifẹhonu han l’Ọṣun
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02983
Yoruba Nation: Gómìnà Akeredolu ní àná Ìgbò ní òun, òun sì tako ìyapa Nàíjíríà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02984
Imam ìjọ Shafaudeen in Islam, Sabit Olagoke gbàdúrà pé kò sí olólùfẹ́ BBC Yorùbá tó máa ṣìrìn lọ́dùn 2023
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02985
Alaafin Aole: Ṣé òótọ́ ni pé èpè Alaafin Aole ń ja Yorùbá títí di òní?
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02986
El-Zakzaky: Àwọn ọmọ Nàìjíría fẹ́ òfin Islam ju ìjọba awarawa lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02987
Ile-ẹjọ sọ eeyan mẹwaa ṣewọn l’Ekiti, idọti ni wọn da soju titi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02988
Oju ti pọn awọn Fulani ju ni Naijiria yii, afi ka tọju wọn atawọn maaluu wọn-Sheikh Gumi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02989
Á júwe ilé fún Niyi Akintola tó bá tẹ̀síwájú láti ṣiṣẹ́ tako wá - APC l‘Oyo
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02990
Nigeria vs Madagascar: Super Eagles ń gbáradì fún ọjọ́ àìkù
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02991
TB Joshua biography: Tí kìí bá ṣe rélùwéè tó bàjẹ́ lójú ọ̀nà, iṣẹ́ ológun ní kò bá ṣe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02992
Abuja rice pyramid fact check: Ẹ̀ka àṣewádìí BBC ti tú isu dé ìsàlẹ̀ kòkò ìrẹsì gogoro tí Ààrẹ Buhari ṣe ìfilọlẹ̀ rẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor